Asiri irawo eda
O dara lati mo nipa iru irawo ti o gbe wa Aiye se irawo INA ni abi
irawo ERUPE abi irawo ATEGUN abi irawo OMI
Mofe ki gbogbo wa mo wipe awon inkan won yi ni se ninu aye eda
pupo ibe lao ti mo iru iwa ti eniyan lewu iru aso tole wo ati iru ise
tole se ati bebelo eyini die ninu awon asiri na
EYI NI AWON IRAWO TI O BA ARA WON MU
1.ARIES
LEO
SAGGITARIUS
Awon eda ti won fi INA seda won
2.TAURUS
VIRGO
CAPRICORN
Awon eda ti won fi ERUPE seda won
3.GEMINI
LIBRA
AQUARIUS
Awon irawo ti won fi ATEGUN seda won
4.CANCER
SCORPIO
PISCES
Awon irawo ti won fi OMI seda won
LATI MO IRU IRAWO TI O WA IRAWO OJO IBI :-
1,(Jan. 20 – Feb. 18 – Aquarius – irawo Afefe)
2,(Feb. 19 – Mar. 20 – Pisces – irawo omi)
3,(Mar. 21 – April 19 – Aries – irawo ina)
4,(April. 20 – May 20 – Taurus – irawo Erupe)
5,(May 21 – June 20 – Gemini – irawo Afefe)
6.(June 21 – July 22 – Cancer – irawo omi)
7,(July 23 – Aug. 22 – Leo – irawo ina)
8,(Aug. 23 – Sept. 22 – Virgo – irawo erupe)
9,(Sept. 23 – Oct. 22 – Libra – Irawo Afefe)
10,(Oct. 23 – Nov. 21 – Scorpio – irawo Omi)
11,(Nov. 22 – Dec. 21 – Sagittarius – irawo ina)
12,(Dec. 22 – Jan. 19 – Capricorn – irawo Erupe)
Wo osu ti ojo ibi re bosi lati mo iru irawo re
Irawo yi ni se pelu arawon ti koba bara won mu larin ore meji Oko
ati aya ajose po won kole fibe dan moran daada
Discussion about this post